Kaabiyesi Olubadan ti ilu Ibadan, Oba Saliu Adetunji ti darapo mo awon baba nla re l’eni odun metalelaadorun (93).
IROYIN YII NA LE WU O LATI KA: E w’oju baba ti oye Olubadan yi kan bayi
Gegebi iko OgunToday se ti gbo, Oba Saliu Adetunji w’aja laaro ojo-sinmi (2-1-2022) ni ile iwosan ijoba, – University College Hospital (UCH) leyin aisan ranpe.
Ojo kerin Osu keta odun 2017 ni won ja’we oye le Kaabiye lori gegebi Olubadan kokanlelogoji (41st Olubadan)