O ba’le gude! Ohun mimu ti n fun’ni l’agbara POWER BLACK ENERGY DRINK wo’le de were

0
1078
Advertisement

Nkan mimu elerindodo ti oruko re n je POWER BLACK ENERGY DRINK ni won ti ko s’ita bi omo ojo mejo l’eko lojo Tuiside ose yi ni ile itura nla Raddisson Blu to wa n’ilu Ikeja.

Orile ede Turkey ni won ti po nkan mimu, POWER BLACK ENERGY DRINK po, ti o si je wipe o se be wa kaakakiri awon orile-ede bii marundinlogoji (35) ni Asia, Europe, Africa ati be be lo. POWER ENERGY DRINK ni akoko iru e l’orile ede yii ti o ni omori ti won n pe ni hygiene cover, iyen eyi ti yoo je ko se e se fun eni to ba n mu POWER BLACK ENERGY DRINK lati le fi de ori agolo na, ti won o ba mu tan leekan soso.

Nibi ikojade ohun, Ogbeni Samuel Ojotobor ti o je olootu itaja fun ile ise Frisson Nigeria Limited ti won n pin POWER BLACK ENERGY DRINK jakejado orile ede Naijiria, so wipe nkan mimu ohun o l’elegbe nile yii.

“Ara oto ni Power Black Energy drink je. Yato si omori hygiene cover ti a n wi yi, nkan mimu ohun dara pupo fun omo Naijiria lati ma a mu nitori wipe on fun’ni l’okun ati agbara lati le se ise-ojo eni d’oba” -Ogbeni Ojotobor lo so be.

Gegebi alukoro ile-ise Frisson Nigeria, Eniola Alawiye se ti so, Power Black Energy Drink ni awon eroja bii Omi to mo kooro lailabawon, Suga glucose syrup, Sodium citrate, Taurine, Fitamin B2, B3, B5 ati B6, leyi to se ara loore pupopupo.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here