
Ariwo ‘oosa boo le gbe’mi, se mi boo se ba mi’ l’awọn omo egbe All Progressives (APC) kan n pa kaakiri lori owo rogbun-rogbun ti won fi ra foomu idibo abele fun ipo alaga ati awon alokoso miran ninu egbe ohin, l’eyi ti won fe ki ẹgbẹ o da pada fun awon nitori pe, awon…
Awon adijedupo ninu ẹgbẹ APC ti kadara o se loore l’awọn fe gba owo awon pada