OmiTeyinWo’gbinL’enu: Oye Olubadan le ma bo s’owo Lekan Balogun mo o. Idi re

0
Gomina ana, Oloye Rasidi Ladoja ni o se e se ko di Olubadan tuntun

E w’oju baba ti oye Olubadan yi kan bayi

0
Gege bi isedale ilu Ibadan, oye Olubadan kii se ti idile kan ni pato bi won ti ma n se ni awon ilu Yoruba...

Keere o…. Olubadan w’aja!

0
Kaabiyesi Olubadan ti ilu Ibadan, Oba Saliu Adetunji ti darapo mo awon baba nla re l’eni odun metalelaadorun (93). IROYIN YII NA LE WU O...

Lori oro Olori Ooni to ja’we fun Kaabiyesi, Elebuibon ni o di dandan ki...

0
Ogbontarigi Babalawo to gbo’fa yanranyanran, to tun je Araba ti ilu osogbo, iyen Baba Yemi Elebuibon ti se afomo oro wipe Olori-k’olori to ba...

Awon Olopa ju Osere tiata s’atimole l’Abule-Egba

0
O se e se ki owo awon olopa ti te gbajugbaja osere tita nni, Damola Olatunji leyin ti o fi esun kan awon agbofinro...

“Abẹrẹ-ajesara lásán o le ko orilẹ-èdè kankan yo nínú laasigbo Omikuronu” -Ajo WHO lo...

0
Ajo to n mojuto ètò ilera l'agbaye, ìyẹn World Health Organisation (WHO) lo ti n kọminu wípé eya korona-fairosi ti wọn n pe Omikuronu...

“On’iro aye at’orun gba-a ni Bisi Akande” –Ayo Adebanjo lo so be

0
Olori egbe Afenifere, Oloye Ayo Adebanjo ti fi enu-ate ba iwe kan ti Aare egbe APC nigba kan ri, Bisi Akande gbe jade l’ose...

Erin wo! Soun Ogbomoso w’aja

0
Kabiyesi, Soun ti ilu Ogbomoso Oba Jimoh Oyewumi (Ajagungbade 1) ti w’aja leyin odun mejidinlaadota (48) ti won ti wa lori apere. Ojo kerilelogun...

“O to iye bi eedegbeta eeyan ti iko-egbe pa l’odun 2020” -Ajo WHO

0
Ajo ti o n moju to eto ilera l'agbaye, iyen World Health Organisation (WHO) so wipe o to iwon 549,000 awon omo bibi ile...

Ijamba ọkọ gb’ẹmi ọmọdekunrin kan ni ona ìbàdàn

0
Oko ajagbe-ejo kan ti te ọmọkùnrin kan pa ni òpópónà marose Eko-si-Ibadan, ti o si tun se awon meta miran lese yanna-yanna. Agbegbe ile-epo...

Stay connected

0FansLike
3,127FollowersFollow
0SubscribersSubscribe
- Advertisement -

Latest article

Abiodun declares war on kidnappers, Yahoo boys

0
…to set up financial crimes agency The Ogun State government has declared war on kidnappers and fraudsters popularly referred to as Yahoo boys. According to the...

Man docked for not providing for his pregnant girlfriend

0
 A 24-year-old man, Korode Yusuf, was on Wednesday docked in an Ota Magistrates’ Court in Ogun for not providing for his pregnant girlfriend. Yusuf, who...

Obasanjo lauds Gov. Abiodun’s housing strides

0
A former President of Nigeria, Chief Olusegun Obasanjo has described the giant strides of Ogun State Governor, Prince Dapo Abiodun in the housing sector...