IROYIN

Osere Ori-Itage, Adio Majesta ti ku o

Won ni aisan ito-suga lo pa a

1.43Kviews

Iroyin ti o n te iko OgunToday lowo fi ye wa wipe osere ori itage Yoruba ti o je agba-oje l’enu ise na, Alagba Gbolahan Adio Majesta ti jade laye.

A gbo wipe Majesta te’rigbaso lojo Isegun ti o koja leyin ti o ti jijakadi pelu arun ito-suga, iyen diabetes.

Oloogbe Majesta bere ise ere ori-itage ni opolopo odun seyin, ni nkan bii odun 1960, o ti kopa ninu opolopo ere onise ti inu sinima.

Leave a Response