IROYIN

Olori omo egbe Yinka Ayefele ti jade l’aye

950views

Iku ti d’oro o, o ti pa olori omo-egbe olorin ilumooka ni, Yinka Ayefele, eni ti awon eeyan mo si Waheed Adekola ti apeje re si n je Waheed Ege.

A gbo wipe Waheed ni o jade l’aye laaro ana, ojo eti, leyin ti o ti wa ninu ile fun bi ojo melo.

Won ni igbe ara-riro ni oloogbe Waheed n pa lati igba ti o ti wa ninu ile ohun fun itoju.

K’Eledua o ma see l’akufa fun egbe Ayefele

Leave a Response