IROYIN

Flying Eagles R’eyin Qatar ninu idije Ife-eye boolu agbaye, Poland 2019

292views

Iko Flying Eagles n’irole-oni, se’gun akeegbe won ti won n s’oju Ile Qatar ninu idije ife-eye boolu agbaye fun awon oje ti ojo ori won ko ju Ogun odun lo.

Idije ohun n waye ni ilu Poland.

Maxwell Effiom ati Okechukwu Offia ni won koko gba boolu s’awon ni ipele kini ifesewonse ohun ti o waye ni ilu kan ti won m pe ni Tychy Stadium.

Ni ipele keji ewe, Tom Dele-Bashiru ati Aliu Salawudeen fi ayo meji miran kun meji akoko lati r’eyin Qatar.

 

Leave a Response