“On’iro aye at’orun gba-a ni Bisi Akande” –Ayo Adebanjo lo so be

0
1129
Advertisement

Olori egbe Afenifere, Oloye Ayo Adebanjo ti fi enu-ate ba iwe kan ti Aare egbe APC nigba kan ri, Bisi Akande gbe jade l’ose to koja. O ni akojopo iro lasan gba a n’iwe ohun je.

Bee ba gbagbe, l’ose to koja ni Alagba Akande ti o ti f’igba kan je gomina ipinle Osun ri, se akojade iwe ohun ni ipinle eko pelu akori “MY PARTICIPATIONS”.

Nibi akojade ohun lo ti t’abuku ba Oloye Adebanjo ati aare ana, Oloye Olusegun Obasanjo ati awon leekan-leekan ni inu oselu orile-ede Naijiriya.

Sugbon olori egbe Afenifere ni kenikeni ma ka oro Akande si rara o, nitoripe ogbon a ti se ipolongo ibo fun Asiwaju Bola Tinubu lati di aare l’odun 2023 ni Akande nda. Ati wipe, o ti han gbangba wipe Akande ati awon eeyan re yooku ninu egbe APC n k’abamo latari bi won se gbe Ajagunfeyinti Buhari de ipo Aare l’odun 2015.

Ori telifisan iroyin kan ti won n pe Arise News TV ni alagba Adebanjo ti se afomo oro ohun lojo tusde yi.

Enu onikan la ti n gb pon-on… “Oniro aye at’orun gba-a l’okurin ti won n pe l’Akande yen. Mi o sese mo gege bi oniro. O ti n pa iro lati ojo to tip e. Ore re, iyen Mojisola Akinfenwa so bi Akande se je oniro to ninu iwe ti Akinfenwa se agbejade re.

“omo-odo Tinubu ni Akande, o si kere si mi gan lati ma a ba ta kangbon-oro

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here